ÌTÀN ÒKÉTÉ.
ÌTÀN ÒKÉTÉ.___Òkété jẹ́ ọ̀kan nínú ẹranko abàmì tó lágbára púpọ̀. A sì máa gbé nínú ihò. ELÉDÙMARÈ fún-un ní àṣẹ púpọ̀.Òkété kìí fi ọwọ́ tàbí ẹṣẹ̀ gbẹ́ ihò, ÌRÙ ni òkété maá n fií gbẹ́ ihò, fún ìdí èyí, ẹ ò le rí èrùpẹ̀ lẹ́nu isà òkété, bí ènìyàn bá gbẹ́ ihò òkété, ìgbà mìíràn […]
Continue Reading